Celestial Hymn Manna for Today (Monday 16 Nov 2026) | Hymn 533: Ayo, ayo, ayo yio wa (Yoruba)

Posted by Admin   •   Nov 16, 2026 12:00 AM   •   Celestial hymn manna
Celestial Hymn Manna for Today (Monday 16 Nov 2026) | Hymn 533: Ayo, ayo, ayo yio wa (Yoruba)
Monday: faith and works

1. Ayo, ayo, ayo yio wa,
Ninu Ijo Mimo yi,
Ekun, wahala yio dopin,
Ninu Ijo Mimo yi.

2. Wahala on iponju,
Mo ti ko won sile,
Gbogbo enyin Ijo Mimo,
E yo, e yo, e yo.

3. Ogo Mi lo si je Ori,
Ninu Ijo Mimo,
Ogo ti awon orun ri,
Ti won si yo titi.

4. Eni to ba si le sin Mi,
Yio si ri ogo na,
Ogo na temi si soro,
Yio si ni igbala. Amin

CCC Hymn 533
8 • 0 • 0
Comments (0)
No comments yet.
Members Online:
0 Members online in last 5 minutes
42 Guests online in last 5 minutes