Evening hymn of forgiveness
1. Gbohun mi, gbohun mi,
Tani mo ni laiye osi yi?
Nigbati 're ba ko mi sile
Tani yio wa gba mi?
2. Tani yio samona mi?
Ninu irin ajo mi,
Ire ni Irawo didan owuro,
Nigba t'ara ba ko mi sile
Jesu yio wa gba mi. Amin.
CCC Hymn 6